This site uses cookies to ensure you get the best experience. Learn more

Sign up or log in to follow your favorite podcasts and listen to episodes!

AWR Yoruba / èdèe Yorùbá

Adventist World Radio, AWR Podcasts
249 episodes
Daily Yoruba radio programs from Adventist World Radio

Disclaimer: the content and artwork of this podcast are the property of its owner and are not affiliated with nor endorsed by Audiotrails.

LO OMI FUN ODE ARA RE; IKU TI O PON DANDAN

E LO OMI FUN ALAAFIA TI O PEYE; A GBODO KU SI ESE KI A TOO LE JERE AYERAYE

MASE MUN OMI NIGBA TI O BA NJEUN LOWO; OO DARA JU LATI FI O ROPO

E MAA MUN OMI TI O TO NI OJOOJUMO; OLORUN FI DAFIDI ROPO SAULU NITORI AIGBORAN RE

OMI; DAFIDI AND SAULU -1

LO OMI NI OPO YANTURU FUN ILERA TI O PEYE; A LEE KO EKO IGBORAN LATI ARA IGBESI-AYE SAULU ATI DAFIDI

TERU-TERU, TIYANUN-TIYANUN NI OLORUN DA WA; EWA NINU RUDU-DUDU

ARA WA LE WO ARA RE SAN; OLORUN LE MUN RERE JADE KURO NINU RUDU-RUDU AYE RE

ALAAFIA PELU OLORUN;

ALAAFIA OLORUN WA NI IBI GBOGBO

DAKE AROYE; MA SE REWESI

DIPO KI A MAA SAROYE, DAWO LE OHUN TI O LEE SE O NI ANFAANI; MASE REWESI NITORI PE O BAKU

AKOKO - OHUN TI O SOWON JULO; ERE RERE

LO AKOKO RE DAADAA; TI A BA SISE FUN OLORUN, A O RI ERE RERE GBA

MAA SE AKOSILE ASEYORI RE; OLORUN NBO AWON TIRE

LATI LO AKOKO RE BI O SE YE, PE ARA RE NIJA NIPA SISE AGBEKALE ISE RE NI OJO KOOKAN; OLORUN A PESE FUN O LABE BO TI WU KO RI

OHUN TI O BURU JU; TAA NI ORE RE - REHOBOAMU

OHUN TI O BURU JU TI O LEE SELE SI ENIYAN NI AKOKO FIFI SOFO; REHOBOAMU KO IMONRAN AWON AGBA, O SI PADANU IJOBA

AKOKO; KOROFO

OLORUN TI FUN ENI KOOKAN WA NI IYE AKOKO KAN NAA, LO TIRE DAADAA; KOROFO NI E LAI SI OLORUN

IDILE LAKOKO

FI AKOKO SILE FUN IDILE RE

KO AKOKUN EKO; EKO LATI ARA ITAN

LATI MASE JE OLUWORAN, O GBODO MAA KO EKO LATI IGBA DE IGBA; LEARN NOT TO GRUMBLE FROM THE ISREALITESKO LATI MASE KUN LATI ARA AWON OMO ISRAELI

TEJUMO ISE RE; PIPAMON FUN ISIN MIMO

ISE ASEKARA DARA; OLORUN PA MOSE MO FUN ILO ARA RE

MASE DOMI TUTU SI OKAN ELOMIRAN; O KO KERE JU FUN ISIN

JE ENI TI O NWA OJUTU SI ISORO ELOMIRAN; OLORUN LO MOSE TO JE ABIGBEYIN

MAA SE AAPON; MASE WA ESAN SUGBON AYO

IPINNU RE NI YOO SO IRU ASEYORI RE; DAFIDI KO WA ISUBU SAULU BI KO SE AABO

ISE OLUWORAN; SORA FUN ENI AMI ORORO OLORUN

JAWO NINU A NJE OLUWORAN; DAFIDI KO PA ENI AMI ORORO OLORUN, IWO NAA BU OLA FUN WON

MASE JE OLUWORAN; ABO TI O DAJU

O LEE SE ASEYORI NIGBA TI A KO BA KAWO BOTAN; OLORUN TI O DAABOBO DAFIDI KURO NI OWO SAULU LE DAABOBO O

MO LEE SE OHUN GBOGBO NINU KRISTI

A LEE BORI IDANWO LATI ARA IRANLOWO KRISTI

IDENA FUN IWAPAPO IDILE; IMOLE LATI ORUN WA

JIJE BABA TABI IYA RERE SI GBOGBO ENIYAN; JESU WA LATI TAN IMOLE SI AYE WA

LILO AKOKO PELU IDILE ; JESU ONIRELE OKAN

LILO AKOKO PELU IDILE LEE MUN ISOKAN WA NINU IDILE; JESU FERAN WA

ISOKAN IDILE; JESU OLUSO-AGUTAN WA

MIMA WA IDUNNUN NIPA OPO ISE SISE; JESU JOWO ARA RE SILE FUN IGBALA WA

MIMUN INU AWON OMO DUN; IWAYA-IJA KRISTI TORI ESE

AKOKO PELU AWON OMO WA NI YOO MUN INU WON DUN; JESU GBADURA KIKAN-KIKAN LATI BORI IDANWO

RIRA NKAN FUN AWON OMO LATI MUN INU WON DUN; AGBELEBU KRISTI

OHUN ORO AYE KO LO NMUN INU AWON OMO DUN; AGBELEBU KRISTI MUN EGUN ESE KURO NI AYE WA

IDIWO; OGBON LATI ORUN WA

ISE ASEKARA LATI FIHAN PE A JE OMO-ODO RERE; TI A BA KA ORO OLORUN TI A SI GBORAN, A LEE NI OGBO LATI ORUN WA

MO LE SE OHUN GBOGBO NINU KRISTI

JESU NFUN WA NI IGBOYA LATI LEE SE OHUN GBOGBO

AWON OHUN TI O NFA SISARE TETETE WA

WIWA OWO AWAJU; JESU, OLUSO-AGUTAN WA; OLE NI SATANI NIGBATI JESU JE OLUSO-AGUTAN WA

IPENIJA TI IDILE NKOJU; ONISEGUN NLA NI

OWO GBOGBO EEYAN LO DI; LO SI ODO KRISTI ONISEGUN NLA NI FUN IWOSAN

JAGIDI-JAGAN; AKASO SI ORUN

JAGIDI-JAGAN A MAA FA IYAPA NINU IDILE; JESU NI AKASO SI ODO OLORUN